Bhadboi oml

Bhadboi OML – Lagos Lyrics

Download | Fast Download

Lagos Lyrics

Always deep inna mi thought, all night long
All I got is hustle o, my saviour, my anchor
Melody yìí na my all, I don rise up
I no fit dey vex for my fellow guy wey buy Lexus

Torí ayé la bá owó
Ayé la bá ọmọ

Ayé to crucify J, ọmọ ọlọrun
Wọn tún pa iró mọ

Ayé la bá olá
Ayé la bá aya

Ṣadé ti fẹ ṣe eléyà pò mó iléyá
Ó tún fẹ ra àbáyà

You want to totori me
Do you want to be a konkobility?
Mi ò dè bá ti eré wá
Na Lagos we dey, opportunity

Mek I totori you
You don’t want to be a konkobility
Mi ò dè bá ti eré wá
Na Lagos we dey, ònà ìlúù mì jìn

Ẹwo bàa ṣé n rìn ní ilé
[?][?][?]
Igi dá lókè
Aféfé ò ní kí ẹyẹ má fò lo

Ẹwú n be lódẹ
Ọmọ ìyá mí, just show me some love
Wèrè po l’èkó
Ọmọ ìyá mí, just show me some love


Ẹwo bàa ṣé n rìn ní ilé
[?][?][?]
Igi dá lókè
Aféfé ò ní kí ẹyẹ má fò lo

Ẹwú n be lódẹ
Ọmọ ìyá mí, just show me some love
Wèrè po l’èkó
Ọmọ ìyá mí, just show me some love

Èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi
Èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi
Èrò mi tó n jó
Èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi

Lu pápá, ebi n pa àlejò
Onílù mi n bẹ nì ìsàlè odò
Olórun ló n bá mi ṣeé, ìgbàyí lolá, ìgbàlódé
Èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi

Listen & share

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *